Saturday, July 6, 2013

IBALOPO OBINRIN SOBINRIN NI ORILE EDE NAIJIRIA IYALENU EETIRI

IBALOPO OBINRIN SOBINRIN NI ORILE EDE NAIJIRIA IYALENU
EETIRI


Ni ti temi mo ni igbagbo wipe ojise olorun chris okotie ni o to
gbangba sun loye ni ode oni (mmo fe kio di mimo wipe emi kii se omo
ijo re, ile isisn miran ni mo nlo) kin ni obi oro yii? Emi alawo
dudu
tii se omo bibi orile ede Amerika tio yan orile ede Naijiria laayo
bi
ilu abinibi re lati bii odun meedogbon. Nitori ohun nikan ni ogun
nagbongbo ojise olorun tio tako atankale asakasa ibalopo laarin
okunrin si okunrin ni orile ede yii. Ojise olorun yii, ni o se ikilo
fun wa ni odun 2002 wipe “ibalopo okunrin sokunrin tin gbogbo
kaakiri’ (Ninu iwe iroyin The new Treasure Magazin ni ojo
kokanlelogun titide ikerindinlogun (odun Alumoni) tio jade ninu osu
agemo ni oju ewe kewa de ikeedogun. Bakanna ninu iwe re The Last
Outcast Ojise Olorun yii kan na ni won so fun mi pe ni igb ekeji
tio
se tako ibalopo laarin obinrin sobinrin gegebi ohun ija esu adun
koko
moni.

Pupo omo orile ede yii ti mo ba fi oro jomitoro oro lori iwa ibaje
ko
tile ni igbagbo wipe asakasa yii nbe lawujo wa latari wipe awon
alawo
funfun nikan ni ibaje yi gbewo bi ewu. Sugbon iwakiwa yii n se jamba
gbemigbemi fun opolopo idi le le yi ti igbehin re silee so gbogbo
awon orile ede wa si oko iparun.
“Orisirisi awon iwe iroyin wa gbogbo ni onse afihan asa buburu yii
bere latori iwe iroyin Fame okiki ojo ojo kerin osu owada (Sept.) ni
odun 2002 pelu akole “Lesbian in Lagos State house (Ibalopo Obinrin
sobinrin ni ilu eko.
Bakanna iwe ikroyi City People (olaju Eniyan) ti ojo keedogun osun
sawere (October) ni odun 2003 pelu akole “Abuja Lesbians Forum Club”
(Alabanilopo laarin obinrin sobinrinAbuja da egbe sile) Eyi si je
ategun fun awon olori ile iwe giga lobinrin lati maafa awon akeko
won
obinrin sinu egbe yii. Iroyin yii jeyo ninu iwe iroyin Sunday
Vanguard to ojo keedogun osu okudu ti odun2003 ni oju ewe
kejilelogun
titi de ikefalelogun (June 15, 2003 P22-23) lati mu iwa ibaje yi wa
sopin ni akoko gbogbo.
Obinrin orile ede yii gbodo doju ija ko iwakiwa yii pelu orisirisi
ona bii adura gbigba gbogbo idile, Ile Iwe papa julo ile iwe
onibagbe
akeko, ipade oluko ati awon obi ati awon omo ile ijosin gbogbo
musulumi ati awon omolehin jesu gbogbo ni Atari wipe iwakiwa yii le
bi orile ede yi wo patapata nipase awon omo wa.

Gbogbo iya gbodo mu eko nipa ibalopo ni okunkundun fun awon omo
won “o gbodo je mimo fun awon omo wa wipe mimo ni eya abe won eyi ti
enikeni ko gbodo se oun kohun pelu je.
Kinidi? Idi eyi ni wipe awon ogo were ode oni awon ore, oga, ati
alabagbe won fa si inu iwakiwa yii (Fun apere iwe iroyin city people
ojo keedogun osu okudu ti odun 2003 ni oju ewe kerinla) se afihan bi
omo odun mefa se di ara awon oniwakuwa yi pelu akole “How I became a
homosexual” (Bi mo se di alabalopookunrin sokunrin)
Gbogbo onise iroyin ni orile ede yii gbogbo gbaradi lati maa tu
asiri
opolopo awon iwakiwa yii awon naa si gbodo gbogun ti iwa ibaje yii
lati lodi si wiwa enikeji fun awon oniwakiwa yii nipase iwe iroyin.

Idun koko moni iwakiwa yii tile poju to aarun Ibalopo kogboogun
AIDS
Ni ayaba omo odun metadinlogbon kan ti ao so siwaju wipe iwakiwa yii
nda abo bo oun lati ma ko arun kogboogun nii AIDS E je kia kilo fun
wipe gbogbo ibalopo laarin eleya ara kanna nipase atenubonu ma nse
okunfa arun kogbogun AIDS ni kiakia ati pelu irorun fun ore at ebi
ti
e ba ka iwakiwa yii mo lowo, e gbodo gba adura fun gidigidi lehin
opolopo ibawi, kie si mu iru eni bee lo si iwaju awon eni olorun fun
itusile ninu igbekun iwakiwa yi.
Awon oyinbo alawo funfun tile ma npa iro funfun wipe abimo ni iwa yi
je fun awon eniyan kan. Ogoro eniyan n wu iwakiwa yii ni ipase olaju
ati idaamu okan tin se adina gboku fun igbogun ti iwakiwa yii.
Iwakiwa le di ohun igbagbe pelu adura ati ohun ija lati inu emi. Eyi
ni ona kan soso gege bi ose ti awon ese nlanla tio ku. Ibalopo
Okunrin si Okunrin yii je nkan to lewu pupo gege bi “se”
Gbogbo iwe ijoba ati adani gbodo ko awon akeko won lati lodi si iwa
yi. Won gbodo se ofintoto lati mu iwakiwa yii laarin ile-iwe ati
ibugbe awon akeeko wa gbogbo.

Ni ipari, mo gbagbo wipe isoro ti n koju ebi gbogbo ni orile ede yii
ni ibalopo Obinrin sobinrin. Emu wa si Ero oko tio fe iyawo ti nwu
iwakiwa yii pelu ore re laihan si oko re (ti o n kigbe wipe kosi
okunrin ti loe temi lorun) Iru aya wo ni eyi je, Iru iyawo wo ni yio
ya? Nje koni mo ko awon omo re ni iwakiwa yi pelu apeere eyi ti asa
ati ise ile alawodudu ko fowo si.

Olorun nife orile ede yii. Olorun nikan ati adura gbogbo eniyan
orile
ede yii ati atunbi awon tio ti se agbako iwakiwa yii nikan lole gba
orile ede yi lowo idaamu apanirun igbehin yi, mo joko nile itawe
omolehin Jesun kan ni Ibadan tio nta nkan mimu ibile kan ti a pe ni
zobo bakanna ni bi mo ti gbadun oun mimu yi ni mo sa deede ri iwe
iroyin awon kirisitieni (Family Encounters) kan pelu akole
yii ” Ibalopo Obinrinsobinrin ni ibi gbogo wan”
“Lakiriboto go de”. Obi gbodo Ji giri.
Mon sokun bi mo ti nka Ibalopo aileto yii pelu eto ni ile iwe
alakobere ati giga pelu iranlowo awon oluko koda ni igbamiran pelu
olori ile iwe ni pa mimu awon omo kekere wo egbe buburu yii
lorekore.
Awa iya orile ede yii gbodo ji giri si ija ati wa egbo dekun fun
iwakiwa yii, eyi ti o mo ju ninu awon ogun mimo lati da aabo to peye
bo awon ogo were wa.

No comments:

Post a Comment